2 Sámúẹ́lì 14:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Obìnrin ará Tékóà náà sì wí fún ọba pé, “Olúwa mi, ọba, jẹ́ kí ẹ̀ṣẹ̀ náà wà lórí mi, àti lorí idilé baba mí; kí ọba àti ìtẹ́ rẹ̀ ó jẹ́ aláìlẹ́bi.”

2 Sámúẹ́lì 14

2 Sámúẹ́lì 14:1-15