2 Sámúẹ́lì 14:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọba sì wí pé, “Ẹnikẹ́ni tí ó bá sọ̀rọ̀ sí ọ, mú Olúwa rẹ̀ tọ̀ mí wá, òun kì yóò sì tọ́ ọ mọ́.”

2 Sámúẹ́lì 14

2 Sámúẹ́lì 14:1-12