2 Sámúẹ́lì 13:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ámúnónì sì banújẹ́ títí ó fi ṣe àìsàn nítorí Támárì àbúrò rẹ̀ obìnrin; nítorí pé wúndíá ni; ó sì ṣe ohun tí ó ṣòro lójú Ámúnónì láti bá a dàpọ̀.

2 Sámúẹ́lì 13

2 Sámúẹ́lì 13:1-8