2 Sámúẹ́lì 13:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì ṣe, lẹ́yìn èyí, Ábúsálómù ọmọ Dáfídì ní àbúrò obìnrin kan tí ó ṣe arẹwà, orúkọ rẹ̀ a sì máa jẹ́ Támárì; Ámúnónì ọmọ Dáfídì sì fẹ́ràn rẹ̀.

2 Sámúẹ́lì 13

2 Sámúẹ́lì 13:1-3