2 Sámúẹ́lì 13:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun sì wí fún un pé, “Kó ha ní ìdí bí! Lílé tí ìwọ ń lé mi yìí burú ju èyí tí ìwọ ti ṣe sí mi lọ.”Ṣùgbọ́n òun kò fẹ́ gbọ́ tirẹ̀.

2 Sámúẹ́lì 13

2 Sámúẹ́lì 13:11-20