2 Sámúẹ́lì 13:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ámúnónì sì kóríra rẹ̀ gidigidi, ìríra náà sì wá ju ìfẹ́ tí òun ti ní sí i rí lọ. Ámúnónì sì wí fún un pé, “Dìde, kí o sì máa lọ!”

2 Sámúẹ́lì 13

2 Sámúẹ́lì 13:12-23