2 Sámúẹ́lì 12:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun yóò sì san àgùntàn náà padà ní mẹ́rinmẹ́rin, nítorí tí ó ṣe nǹkan yìí àti nítorí tí kò ní àánú.”

2 Sámúẹ́lì 12

2 Sámúẹ́lì 12:1-13