2 Sámúẹ́lì 12:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìbínú Dáfídì sì fàru gidigidi sí ọkùnrin náà; ó sì wí fún Nátanì pé, “Bí Olúwa ti ń bẹ láàyè: ọkùnrin náà tí ó ṣe nǹkán yìí, kíkú ni yóò kú.

2 Sámúẹ́lì 12

2 Sámúẹ́lì 12:4-12