2 Sámúẹ́lì 12:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nátanì sì lọ sí ilé rẹ̀ Olúwa sì fi àrùn kọlu ọmọ náà tí obìnrin Úráyà bí fún Dáfídì, ó sì ṣe àìsàn púpọ̀.

2 Sámúẹ́lì 12

2 Sámúẹ́lì 12:8-17