2 Pétérù 2:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tí ó sọ àwọn ìlú Sódómù àti Gòmórà di eérú, nígbà tí ó fi ìparun pátapáta dá wọn lẹ́bí, tí ó fi wọ́n ṣe àpẹẹrẹ fún àwọn tí yóò jẹ́ aláìwà-bí-Ọlọ́run.

2 Pétérù 2

2 Pétérù 2:1-9