2 Pétérù 2:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí òun kò si dá ayé ìgbàanì sí, nígbà tí ó mú ìkún omi wá sórí ayé àwọn aláìwà-bí-Ọlọ́run, ṣùgbọ́n ó pa Nóà mọ́, oníwàásù òdodo, pẹ̀lú àwọn ọmọ méje mìíràn.

2 Pétérù 2

2 Pétérù 2:1-7