2 Ọba 9:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jéhù dìde sókè, ó sì wọ inú ilé lọ. Nígbà náà, wòlíì náà da òróró náà sórí Jéhù; ó sì wí pé, “Èyí ni ohun tí Olúwa Ọlọ́run Ísírẹ́lì wí: ‘Èmi fi àmì òróró yàn ọ́ ní ọba lórí àwọn ènìyàn Olúwa Ísírẹ́lì.

2 Ọba 9

2 Ọba 9:5-13