2 Ọba 9:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí ó dé, ó rí àwọn olórí ẹgbẹ́ ọmọ ogun tí wọ́n jókòó papọ̀. “Èmi ní iṣẹ́ fún ọ, olórí,” Ó wí.“Fún èwo nínú wa?” Jéhù béèrè.“Fún ọ, Alákóso,” Ó dáhùn.

2 Ọba 9

2 Ọba 9:1-13