2 Ọba 3:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jéhórámù ọmọ Áhábù ó sì di ọba Ísírẹ́lì ní Ṣamáríà ní ọdún kejìdínlógún ti Jéhósáfátì ọba Júdà, ó sì jọba fún ọdún méjìlá.

2 Ọba 3

2 Ọba 3:1-4