2 Ọba 24:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ti ìyókù iṣẹ́ ìjọba Jéhóíákímù, àti gbogbo nǹkan tí ó ṣe, ṣé wọn kò kọ wọ́n sínú ìwé ìtàn ọba Júdà?

2 Ọba 24

2 Ọba 24:1-6