2 Ọba 21:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n sì sin ín sínú isà òkú nínú ọgbà Úṣà. Jòṣíáyà ọmọ rẹ̀ sì jọba ní ipò rẹ̀.

2 Ọba 21

2 Ọba 21:23-26