2 Ọba 21:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì ṣe búburú ní ojú Olúwa, ó sì tẹ̀lé iṣẹ́ ìríra tí àwọn orílẹ̀ èdè tí Olúwa lé jáde níwájú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.

2 Ọba 21

2 Ọba 21:1-8