2 Ọba 21:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mánásè jẹ́ ẹni ọdún méjìlá nígbà tí ó bẹ̀rẹ̀ sí ìjọba, ó sì jọba ní Jérúsálẹ́mù fún ọdún márùndínlọ́gọ́ta (55). Orúkọ ìyá rẹ̀ sì ni Héfisíbà.

2 Ọba 21

2 Ọba 21:1-5