2 Ọba 21:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ti iṣẹ́ ìyókù ti ìjọba Mánásè, àti gbogbo ohun tí ó ṣe, àti fún ẹ̀ṣẹ̀ tí ó ṣẹ̀, ṣé wọ́n kò kọ wọ́n sínú ìwé ìtàn àwọn ọba Júdà?

2 Ọba 21

2 Ọba 21:8-26