2 Ọba 17:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbogbo eléyìí ṣẹlẹ̀ nítorí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ti dẹ́sẹ̀ sí Olúwa Ọlọ́run wọn, ẹni tí ó mú wọn jáde ní Éjíbítì lábẹ́ agbára Fáráò ọba Éjíbítì. Wọ́n sin ọlọ́run mìíràn

2 Ọba 17

2 Ọba 17:1-8