2 Ọba 17:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọba Ásíríà gòkè wá sí gbogbo ibi ilé náà, ó sì lọ sí Samáríà, ó sì dúró tìí fún ọdún mẹ́ta.

2 Ọba 17

2 Ọba 17:1-11