2 Ọba 17:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti pẹ̀lú, Júdà kò pa òfin Olúwa Ọlọ́run wọn mọ́. Wọ́n tẹ̀lé ìhùwàsí àwọn Ísírẹ́lì tí wọ́n ṣe.

2 Ọba 17

2 Ọba 17:18-22