2 Ọba 15:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ásáríyà sinmi pẹ̀lú àwọn baba a rẹ̀. A sì sin ín sí ẹ̀bá wọn ní ìlú ńlá ti Dáfídì. Jótamì ọmọ rẹ̀ sì rọ́pò rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ọba.

2 Ọba 15

2 Ọba 15:1-13