2 Ọba 15:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Fún ti ìyókù iṣẹ́ nígbà ìjọba Ásáríyà, pẹ̀lú gbogbo ohun tí ó ṣe, ṣé a kò kọ wọ́n sínú ìwé ìtàn ayé àwọn ọba Júdà.

2 Ọba 15

2 Ọba 15:3-12