2 Ọba 15:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ménáhémù sinmi pẹ̀lú àwọn baba rẹ̀. Pékáhíà ọmọ rẹ̀ sì rọ́pò rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ọba.

2 Ọba 15

2 Ọba 15:18-31