2 Ọba 15:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Fún ti ìyókù iṣẹ́ nígbà ìjọba Ménáhémù, àti gbogbo ohun tí ó ṣe, ṣé a kò kọ wọ́n sínú ìwé ìtàn ayé ọba Ísírẹ́lì?

2 Ọba 15

2 Ọba 15:18-29