2 Ọba 14:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Fún ti ìyókù iṣẹ́ rẹ̀ nígbà ìjọba Ámásáyà, ṣé a kò kọ wọ́n sínú ìwé ìtàn ayé àwọn ọba Júdà?

2 Ọba 14

2 Ọba 14:11-20