2 Ọba 14:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ámásáyà ọmọ Jóásì ọba Júdà gbé fún ọdún mẹ́ẹ̀dógún lẹ́yìn ikú Jéhóásì ọmọ Jéhóáhásì ọba Ísírẹ́lì.

2 Ọba 14

2 Ọba 14:15-27