2 Ọba 13:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jéhóáhásì sinmi pẹ̀lú àwọn baba rẹ̀. A sì sin ín sí Samáríà, Jéhóásì ọmọ rẹ̀ sì rọ́pọ̀ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ọba.

2 Ọba 13

2 Ọba 13:2-11