2 Ọba 13:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Fún ti ìyókù ìṣe Jéhóáhásì fún ìgbà, tí ó fi jọba, gbogbo ohun tí ó ṣe àti àṣeyọrí rẹ̀ ṣé a kò kọ wọ́n sínú ìwé ìtàn ayé àwọn ọba Ísírẹ́lì?

2 Ọba 13

2 Ọba 13:2-11