2 Ọba 10:34 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Fún ti òmìíràn ti iṣẹ́ ìjọba Jéhù, gbogbo ohun tí ó ṣe, gbogbo àṣeyọrí rẹ̀, ṣé a kò kọ wọ́n sí inú ìwé ìtàn ayé àwọn ọba Ísírẹ́lì?

2 Ọba 10

2 Ọba 10:33-36