2 Kọ́ríńtì 8:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwa sì ti rán arákùnrin wa pẹ̀lú wọn, ẹni tí àwa rí dájú nígbà púpọ̀ pé ó ní ìtara nínú ohun púpọ̀, ṣùgbọ́n ní isínsnyìí ni ìtara rẹ̀ túbọ pọ̀ sí i nípa ìfọkàntàn ńlá tí ó ní sí yín.

2 Kọ́ríńtì 8

2 Kọ́ríńtì 8:21-23