2 Kọ́ríńtì 8:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwa ń gbérò ohun rere, kì í ṣe níwájú Olúwa nìkan, ṣùgbọ́n níwájú ènìyàn pẹ̀lú.

2 Kọ́ríńtì 8

2 Kọ́ríńtì 8:14-24