2 Kọ́ríńtì 6:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ má ṣe fí àìdọ́gba dàpọ̀ pẹ̀lú àwọn aláìgbàgbọ́: nítorí idápọ̀ kín ni òdodo ní pẹ̀lú àìṣòdodo? Ìdápọ̀ kín ni ìmọ́lẹ̀ sì ní pẹ̀lú òkùnkùn?

2 Kọ́ríńtì 6

2 Kọ́ríńtì 6:12-17