2 Kọ́ríńtì 6:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní sísán padà, ní ọ̀nà tí ó dára, (èmi ń sọ bí ẹni pé fún àwọn ọmọdé) ẹ̀yin náà, ẹ ṣí ọkàn yín payá pẹ̀lú.

2 Kọ́ríńtì 6

2 Kọ́ríńtì 6:6-17