2 Kọ́ríńtì 4:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A ń ṣe inúnibíni sí wa, ṣùgbọ́n a kò kọ̀ wá sílẹ̀; a ń rẹ̀ wá sílẹ̀ ṣùgbọ́n a kò pa wá run.

2 Kọ́ríńtì 4

2 Kọ́ríńtì 4:7-18