2 Kọ́ríńtì 4:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A ń pọ́n wa lójú níhà gbogbo, ṣùgbọ́n ara kò ni wá: a ń dàámú wa, ṣùgbọ́n a kò sọ ìrètí nù.

2 Kọ́ríńtì 4

2 Kọ́ríńtì 4:1-10