2 Kọ́ríńtì 3:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwa há tún bẹ̀rẹ̀ làti máa yín ara wá bí? Tàbí àwa ha ń fẹ́ ìwé ìyìn sọ́dọ̀ yín, tàbí làti ọ̀dọ̀ yín gẹ́gẹ́ bí ẹlòmíràn tí ń ṣe?

2 Kọ́ríńtì 3

2 Kọ́ríńtì 3:1-3