2 Kọ́ríńtì 2:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Fún àwọn kan, àwa jẹ́ òórùn ikú sí ikú, àti fún àwọn mìíràn òórùn ìyè sí ìyè. Ta ni ó há si tọ́ fún nǹkan wọ̀nyí?

2 Kọ́ríńtì 2

2 Kọ́ríńtì 2:11-17