2 Kọ́ríńtì 2:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí òórùn dídùn Kírísítì ni àwa jẹ́ fún Ọlọ́run, nínú àwọn tí a ń gbàlà àti nínú àwọn tí ó ń ṣègbé:

2 Kọ́ríńtì 2

2 Kọ́ríńtì 2:12-17