2 Kọ́ríńtì 12:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi mọ ọkùnrin kan nínú Kírísítì ní ọdún mẹ́rìnlá sẹ́yin, yálà nínú ara ni, èmi kò mọ̀; tàbí kúrò nínú ara, èmi kò mọ̀; Ọlọ́run mọ̀: a gbé irú ènìyàn bẹ́ẹ̀ lọ sí ọ̀run kẹta.

2 Kọ́ríńtì 12

2 Kọ́ríńtì 12:1-9