2 Kíróníkà 9:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kìnnìún méjìlá dúró lórí àtẹ̀gùn mẹ́ta, ọ̀kan àti ní ìhà olúkúlùkù àtẹ̀gùn kò sì sí irú rẹ̀ tí a ti ṣe rí fún ìjọba mìíràn.

2 Kíróníkà 9

2 Kíróníkà 9:17-29