2 Kíróníkà 9:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìtẹ́ náà sì ní àtẹ̀gùn mẹ́fà, àti pẹ̀lú àpóti ìtìsẹ̀ wúrà kan ni a dè mọ́ ọn. Ní ìhá méjèèjì ibi ìjókòó ní ó ní ìropá, pẹ̀lú kìnnìun tí ó dúró lẹ́bàá olúkúlùkù wọn.

2 Kíróníkà 9

2 Kíróníkà 9:17-20