2 Kíróníkà 4:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó ṣe agbada dídà ńlá tí ó rí róbótó ìgbọ̀nwọ́ mẹ́wàá láti etí kan dé etí èkejì ìgbọ̀nwọ́ márùn ún sì ni gíga rẹ̀.

2 Kíróníkà 4

2 Kíróníkà 4:1-11