2 Kíróníkà 4:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó se pẹpẹ idẹ, ogún ìgbọ̀nwọ́ ní gígùn, ogún ìgbọ̀nwọ́ ní fífẹ̀ àti ìgbọ̀nwọ́ mẹ́wàá fún gíga.

2 Kíróníkà 4

2 Kíróníkà 4:1-7