2 Kíróníkà 4:14-16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

14. Ó sì ṣe àgbéró ó sì ṣe agbada sí orí wọn;

15. Agbada ńlá kan àti màlúù méjìlá lábẹ́ rẹ̀;

16. Àwọn ìkòkò àti ọ̀kọ̀ àti àmúga ẹran àti gbogbo ohun èlò tí ó fara pẹ́ẹ.Gbogbo ohun èlò ti Húrámí-bì fi idẹ dídán ṣe fún Sólómónì ọba, fún ilé Olúwa jẹ́ idẹ dídán.

2 Kíróníkà 4