2 Kíróníkà 36:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sedekíáyà sì jẹ́ ẹni ọdún mọ́kànlèlógún. Nígbà tí ó di ọba, ó sì jẹ ọba ní Jérúsálẹ́mù fún ọdún mọ́kànlá.

2 Kíróníkà 36

2 Kíróníkà 36:9-15