2 Kíróníkà 36:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní àmọ́dún, ọba Nebukadínsárì ránsẹ́ síi ó sì mú-un wá sí Bábílónì, pẹ̀lú ohun èlò dáradára láti ilé Olúwa, ó sì mú arákùnrin Jehóíákínì, Sedekíà, jọba lórí Júdà àti Jérúsálẹ́mù.

2 Kíróníkà 36

2 Kíróníkà 36:8-11