2 Kíróníkà 35:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbogbo iṣẹ́ náà, àti ìbẹ̀rẹ̀ títí dé òpin ni a kọ sínú ìwé àwọn ọba Ísírẹ́lì àti Júdà.

2 Kíróníkà 35

2 Kíróníkà 35:25-27