2 Kíróníkà 30:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní Júdà pẹ̀lú, ọwọ́ Ọlọ́run wá láti fún wọn ní ọkàn kan láti pa òfin ọba mọ́ àti tí àwọn ìjòyè, nípa ọ̀rọ̀ Olúwa.

2 Kíróníkà 30

2 Kíróníkà 30:5-16